Skip to content
iAfrika – Yoruba
  • Itumọ Àlá
  • Oríkì

Adémọ́lá Ọmọ Erinjogúnọlá

Oríkì Adémọ́lá

Adémọ́lá Ọmọ Erin jogún ọláỌmọ Ọ̀tẹ̀mìkànỌmọ obìnrin sọ̀wà nùÓ lóun kò mórí ọkọ wáiyé;Ohun tákíyẹ̀yẹ́ ń fi sọkọ rẹ̀,Kò wí fẹ́nìkan

Tags Adémọ́lá Ọmọ Erinjogúnọlá, Ọmọ Ọ̀tẹ̀mìkàn
© iAfrika 2026