Àlá ìṣẹ́gun / bíborí ìṣòro
Ó ṣe pàtàkì kí o mọ̀ pé tí o bá ń lálàá kan léraléra, tí o ò si mọ ìtumọ̀ rẹ̀, Àlá náà le sọ nǹkan tí ó máa ṣẹlẹ̀, ó sì ṣe pàtàkì kí o mọ ìtumọ̀ àlá náà. Ní ọ̀pọ̀ ìgbà àlá máa ń jẹ́ ọ̀nà tí àwọn babańlá fi ń bá ẹ …

Tí o bá lálàá nípa ejò, o le jẹ́ àpẹẹrẹ búburú fún ọjọ́ iwájú. Ó lè túmọ̀ sí pé inú àwọn babańlá kò dùn sí ẹ, tí ẹnìkan sì fẹ́ dà ẹ́, àgàgà tí ejò náà bá bù ẹ́ jẹ. Àlá nípa oríṣi ejò le ní ìtumọ̀ tó yàtò sí ara wọn:
Tí o bá lálàá pé o jẹ́ èrò nínú ọkọ̀ kan tí ó ń gbé ọ lọ̀ lórí eré, ó sáábà máa ń túmọ̀ sí àpẹẹre oríire àti àṣeyọrí. Ṣùgbọ́n tí ó bá jẹ́ pé ìwọ ní ò ń wa ọkọ̀ náà, o lè túmọ̀ sí pé o máa pàdánù owó ní ọjọ́ iwájú.
Àla nípa omi le túmọ̀ sí oríṣiríṣi nǹkan, ní ti dáadáa àti àìdáa. Ó ṣeéṣe kó dálé ipò àìbalẹ̀-ọkàn àti ìfòyà tí ò ń là kọjá, nítorí àwọn ìṣẹ̀lè àìròtẹ́lẹ̀ tó ṣẹlẹ̀. Omi tún le jẹ́ àpẹẹrẹ àwọn èrò òdì bíi ẹrù tàbí ìgbèrò ibi àti àwọn èròkerò pẹ̀lú ìmọ̀sílárá ibi tí a ògbé kúrò …
Àwọn àlá tó tọ́ka sí oyún níní: Àwọn mìíràn máa ń lá àlá nípa oyún ara wọn, ṣùgbọ́ ní òpọ̀ ìgbà ẹlòmírà ni o máa ń lá àlá yìí nípa ẹni tí ó máa lóyún. Àlá lè wáyé ní ọ̀nà mìíràn báyìí, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé o ti lóyùn tí gbogbo ènìyàn sì ti …