Tí o bá lálàá nípa ẹyin, ó lè túmọ̀ sí pé o má ṣe àṣeyọrí ní ẹnu iṣẹ́ tàbí ní ilé-ẹ̀kọ́. Amọ́ṣa, tí àwọn ẹyin náà bá ti bàjẹ́, ó le túmọ̀ sí pé ó ṣeéṣe kí o rí wàhálà ní ayé rẹ. Tí àwọn ẹyin náà bá dáa, o túmọ̀ sí pe o máa ṣe àṣeyọrí lórí èròńgbà rẹ.